Èèyàn kan láti ìdílé náà ṣàlàyé fún BBC bí ìjàmbá iná náà ṣe gbẹ̀mí ẹ̀gbọ́n rẹ̀ àtàwọn ẹbí rẹ̀, tó fi mọ́ àwọn èèyàn mẹ́ta ...
Fún ọdún mẹ́wàá, ilé oní yàrá méjì (two-bedroom) ni wọ́n ń gbé ní agbègbè Yaba ní ìpínlẹ̀ Eko. Ilé ìgbé wọn yìí kò jìnà sí ...